Home orisiirisii Arákùnrin ti gbógùn jẹ.
orisiirisii - Orisirisi - August 23, 2019

Arákùnrin ti gbógùn jẹ.

 

Leyin wakati die ti arakunrin omo Nigeria ti n je Erestus Okpe lori Facebook gbe aworan majele si ibi aworan re, ni awon molebi ati awon ore re ni o ti ku.

Bi o tile je pe awon re pe ere lasan ni aworan majele naa, won so fun awon egbin re nigba ti ko fesi si iranse won.

Awon eg on re si lo si ile re ni Maiduguri nibi ti won ti ba oku re. Iku re ya awon eeyan lenu nitori won ko mo idi ti o hu iwa naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…