Home orisiirisii Wọ́n ti mú olè
orisiirisii - Orisirisi - August 22, 2019

Wọ́n ti mú olè

 

Won ti mu arakunrin kan ti o gbiyanju ati ji Plasma TV ni ile itura kan ni Markurdi, ipinle Benue.

Won ka TV naa mo lowo nigba ti o gbe si inu apo irinajo(travelling bag)kan, ti awon oluso ile itura naa si da dura lati se ayewo eru re. Vera Iyo, lo so eyi lori Facebook lati kilo fun awon ti won ni ile itura lati maa sora nitori ete tuntun ti awon ole naa n lo ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…