Toyin Abraham ti sọ orúkọ ọmọ rẹ̀.
Toyin Abraham ti so oruko omo re okunrin.
Onsere naa ti o bimonfun onsere egbe re, Kolawole Ajeyemi, ti ni IRE ni oruko omo awon.
O so lori Instagram pe “awon dupe fun gbogbo ife, ebun ati ike ti awon ti ri lati igba yi awon ti bi omo awon, IRE. Ife naa po, ike naa po, bee si ni ebun naa po. Mo gbadura pe olorun a san esan rere fun gbogbo wa. A si ma jo ma yo ninu oluwa titi aye.
“BABA ATI MAMA IRE”.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…