Home orisiirisii Ruth Kadiri ti bímọ.
orisiirisii - Orisirisi - August 22, 2019

Ruth Kadiri ti bímọ.

 

Gbajumo osere onitiata, Ruth Kadiri ti bimo akoko.

Ruth ati oko re, Ogbeni Ezerika se igbeyawo won ni November 2018.

Ruth ti darapo mo Toyin Abraham ati Ronke Odusanya ti won bimo ni osu ti a wa yii.

Won ku ori ire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…