Home orisiirisii Bàbá ti lu ọmọ rẹ̀ pa.
orisiirisii - Orisirisi - August 22, 2019

Bàbá ti lu ọmọ rẹ̀ pa.

 

Baba kan ti lu omo re ti o je omo odun mewaa titi emi fi bo lara re ni Akure, ipinle Ondo lanaa August 21.

Arakunrin kan ti n je @YemieFASH lo gbe isele naa si ori Twitter, o ni obinrin kan lo gbe oku omo naa lo si ile iwosan ti Akure, amo bi o se gbompe won ni omo naa ti dake, lo b salo pelu oku omo naa.

Won ti se iwadii bi won se ma ri arabinrjn naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…