Bàbá ti fi ìyà jẹ ọmọ rẹ̀.
Baba ti lu omo re titi omo naa o fi riran dada mo, o fi wire na omo re omo dun mewaa nitori o je ki akaba jabo ni agbegbe Ikotun. Oju kan ni omo naa fi n riran bayii.
@emeraldfoots lo gbe isele naa si ori instagram.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…