Àwọn ará Ọ̀yọ́ ti yarí.
Awon agbalagba kookan ti fi ehonu han loju titi nipa bi won se yan omo odun metadinlogbon gege bi komisona.
@PatriotAwaking lo gbe isele naa si ori Twitter, o ni awon agbalagba ilu ni won fi ehonu han nipa bi won se yan Seun Fakorede gege bi komisona fun odo ati ere idaraya.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…