Home orisiirisii Agbábọ́ọ́lù obìnrin ọmọ Nigeria ti kú.
orisiirisii - Orisirisi - August 22, 2019

Agbábọ́ọ́lù obìnrin ọmọ Nigeria ti kú.

 

Ifeayin Chiejine, agbaboolu tele fun Nigeria ti ku.

Gege bi gbolohun ti Nigeria Football Federation NFF fi kale ni ojo Thursday August 22, Chiejine ku leyin ti o se aisan ranpe kan ni ojo Wednesday August 21.

Ki o to ku, o n gba boolu fun SSVSM-Kirat Almaty ni Kazakhstani.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…