Home orisiirisii Ọkọ àti ìyàwó ti gbẹ́ẹ̀mí mì.
orisiirisii - Orisirisi - August 21, 2019

Ọkọ àti ìyàwó ti gbẹ́ẹ̀mí mì.

 

Won ti ri oku oko ati iyawo ni ile won ni ipinle Niger lonii August 21.

Gege bi iroyin se so, oko ati iyawo naa lo si ibi ise won ni ana August 20, ti won si pada si ile. Amo ni aaro oni ni won ba oku won ninu ile. Won o ti mo nnkan to fa iku won. Amo won ti sin won gege bi esin musulumi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…