Fashola kìí se minisita iná mó.
Babatunde Fashola kii se minisita ina (power) mo. Nigba ti won n se inagije awon miniwni ọsan oni, Aare Buhari kede Sale Mamman ti o je omo ile Taraba gege bi minisita ina.
Amo Fashola si di ipo re gege bi minisita ise ati ile mu.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…