Ẹ̀yin ọmọ Èkó, ẹ ti dá’ràn – Babatunde Olalere Gbadamosi.
Eni ti n dije fun ipo gomina tele, Babatunde Gbadamosi ti fesi si bi won se yan Joe Igbokwe gege bi onimoran(Special Adviser) fun Drainage and Water Resources.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…