Home orisiirisii Àwòrán láti ibi ìsìnkú Rev Fr Offu.
orisiirisii - Orisirisi - August 21, 2019

Àwòrán láti ibi ìsìnkú Rev Fr Offu.

 

Won ti se isinku Reverend Father Paul Offu ti won fi esun kan awon fulani ti n sin maalu pe won pa a ni Ihe-Agbudu Road ni Agwu ni ojo Thursday, August1,niHoly Ghost Cathedral ni Enugu ni ana August 20.

Gomina ipinle ilu naa ati Catholic faithful ipinle naa lo wa nibi isinku naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…