Home orisiirisii Àwọn tí ń jẹ owó táàsì.
orisiirisii - Orisirisi - August 21, 2019

Àwọn tí ń jẹ owó táàsì.

 

Federal Inland Service (FIRS) ti gbe oruko awon ti n je owo taasi sita ni ojo Monday August 19, awon ti won te oruko won nza to 19,901, laaarin won ni ile ise ati enikan sooso wa.

Aon ti won ni account naa ní Obasanjo Farms Nig.Ltd (Feedmill); Iyiola Omisore and Par; Citiroof Aluminium Co. Ltd; Coldstone Creamery Limited (Yaba); Davido Music Worldwide Ltd; ati awon yooku miiran, won ti fun won ni ojo mokandinlogbon lati fi san owo na, aijebe won ma yo o ninu account won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…