Home iroyin Aare Buhari ti yan àwọn minisita metalelogiji.
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 21, 2019

Aare Buhari ti yan àwọn minisita metalelogiji.

 

Aare Buhari ti yan awon minisita metalelogiji ni osan, oruko won ati ipo won naa si ni wonyi,

Abia- Uchechukwu Samson Ogah: Minisita fun igbaja Mines ati Steel ipinle
Adamawa- Mohammed Musa Bello: Minisita fun Federal Capital Territory
Akwa Ibom- God’swill Akpabio: Minisita fun Niger Delta
Anambra- Dr Chris Ngige: Minisita fun ise owo(labour) ati ise(employment)
Anambra – Sharon Ikeazu: Minisita fun ayika(environment) ipinle
Bauchi- Adamu Adamu: Minisita fun Eko
Bauchi- Ambassador Mariam Kategu: Minisita fun karakata ati isowo ipinle( state trade and investment)
Bayelsa-Timipre Sylvia:Minisita fun epo ipinle (state petroleum resources)
Benue- George Akume: Minisita fun ise ti o pataki ati oke okun
Borno- Mustapha Baba Shahuri: Minisita fun ogbin ati igbeja awujo
Cross River- Godfi Jeddi: Minisita fun ina ipinle
Delta – Festus Keyamo: Minisita fun ipinle Niger Delta
Ebonyi – Ogbonnaya Onu: Minisita fun siensi ati tekinoloji
Edo- Osagie Ehanire: Minisita fun Ilera
Edo- Clement Agba: Minisita fun bojeti ipinle ati national planning
Ekiti – Otunba Adeniyi Adebayo: Minisita fun industry,trade ati investment
Enugu- Geoffrey Onyeama, Minisita fun foreign investment
Imo- Emeka Nwajiuba: Minisita fun Eko ipinle.
Jigawa- Sulaiman Adamu: Minisita fun omi
Kaduna- Zianab Ahamed: Minisita fun finansi
Kaduna- Mohammed Mahmud: Minisita fun Awujo
Kano- Sabo Nanono: Minisita fun ogbin ati igbeja awujo
Kano-Major Bashir Magashi: Minisita fun difensi
Katsina- Hadi Sirika: Minisita fun afiason
Kebbi- Abubakar Malami: Attorney General ati Minisita fun Justice
Kogi- Ramatu Tijani : Minisita fun ipinle FCT
Kwara- Lai Mohammed : Minisita fun Infomason
Kwara- Gbemisola Saraki: Minisita fun ilera ipinle
Lagos- Babatunde Fashola: Minisita fun Ise ati Ile
Nasarawa- Mohammed Abdullahi : Minisita fun siensi ati tekinoloji ipinle
Niger-Zubairu Dada:Minisita fun oro oke okun ipinle
Ogun-Olamilekan Adegbite: Minisita fun Mines and Steel Development
Ondo- Tayo Alaosuadura : Minisita fun labour ati employment ipinle
Osun- Rauf Aregbesola : Minisita fun interior
Oyo- Sunady Dare:Minisita fun odo ati ere idaraya
Plateau -Paulen Tlen: Minisita fun oro obinrin
Rivers- Rotimi Amaechi : Minisita fun irinse(transportation)
Sokoto- Maigarai Dingyadi: Minisita fun oro olopaa
Tarab- Saleh Mamman: Minisita fun ise
Yobe- Abubakar Aliyu: Minisita fun ise ati ile ipinle
Zamfara- Sadiya Umar Farouk :Minisita fun Humanitarian affair ati National Disaster

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…