Home orisiirisii Ààrẹ Buhari ti fọwọ́ si láti dípò àwọn olórí.

Ààrẹ Buhari ti fọwọ́ si láti dípò àwọn olórí.

 

Aare Buhari ti fowo si lati dipo awon olori Federal government agencies ti won yan gege bi minisita.

Won yan Senator Basheer Garba Mohammed gege bi Federal Commisioner, Natiomal Commission for Refugees, Migrants and Internally Displaced Persons. Won fi dipo Sadiya Umar Farouk.

Won ti yan Dr. Chioma Ejikeme gege bi Akowe( Executive Secetary), Pension Transitional Arrangement Directorate, won fi dipo Sharon O. Ikeazor, won si fi Kashifu Inuwa Abdullahi gege bi Director-General/CEO, National Information Technology Development Agency.

Fun Excutive Commissioner (Stakeholder Management) Nigerian Communications Commission (NCC), Aare Buhari ti fi oruko Adeleke Moronfolu Adewolu ranse si Senate lati dipo Sunday Akin Dare.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…