Home orisiirisii Suicide: Ọlọ́pàá ti gb ẹ̀mí ara rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́.
orisiirisii - Orisirisi - August 20, 2019

Suicide: Ọlọ́pàá ti gb ẹ̀mí ara rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́.

 

Olopaa kan ni orile ede Ghana ti fi ibon ara re pa ara re lenu ise ni ojo Monday, August 19.

Gege bi GhanaWeb se so, Lance Corporal Alhassan Asare ti o wa ni AkrimSwedru ni Brim South ni Easten Region fi irin ise ara re gba emi ara re. O lo si ibi ise re ni ago márùn-ún koja iseju marundinlaadota irole ni Dukes Petroleum Fuel station nibi ti won ti ri oku re.

Won ri Lance Corporal Alhassan ni ori aga pelu apa ibon ati eje ni gbogbo ara re. Won ba ibon re ni aarin itan re ti o koju si ori re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…