Home orisiirisii Suicide: Akẹ́kọ̀ọ́ ti pa ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 20, 2019

Suicide: Akẹ́kọ̀ọ́ ti pa ara rẹ̀.

 

Akekoo olodun ioari ni ile iwe giga Tai Solarin University of Education ti o wa ni ipinle Ogun ti pa ara re ni ojo Monday August 19.

A gbo pe akekoo naa ti n je Ogunbanwo Emmanuel pokun so nitori aise dada ninu idanwo re. Aisa dada ninu idanwo naa o fun ni aaye lati se teaching practice pelu awon elegbe re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…