Home iroyin Seyi Makinde ti yan Kọmíṣọ́nà tuntun.

Seyi Makinde ti yan Kọmíṣọ́nà tuntun.

 

Gomina ipinle Oyo, Seyi Makinde n sa gbogbo ipa re lati se koriya fun awon odo, eyi waye leyin ti o yan omo odun mokanlelogbon, Adebo Ogundoyin gege bi speaker house of assembly. Leyin eyi ni o tun yan omo odun metadinlogbon, Seun Fakorede gege bi Komisona.

Fakorede je giraduati Obafemi Awolowo University (OAU) ni eka civil engineering, o setan ni odun 2016. O je onisowo o si tun je onkowe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…