Home iroyin EFCC ti lọ sí ilé Akinwunmi Ambode.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 20, 2019

EFCC ti lọ sí ilé Akinwunmi Ambode.

EFCC ti lọ sí ilé Akinwunmi Ambode.

Awon osise Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) ti lo si ile gomina ipinle Eko ana, Akinwunmi Ambode.

Awon osise naa lo si ike Ambode ti o wa ni Epe ni won lo ni ago mesan-an aaro oni, won si n tu ile re. Agbenuso EFCC, Tony Orilade lo fi idi eri isele naa mule fun TheCable.

Iwadii naa waye leyin ose die ti EFCC gba aye lati de bank account ti won ni Ijoba ipinle Eko ko nii fun esun jibiyi 9.9 billion naira. Account meteeta naa ni First City Monumeny Bank, Access Bank ati Zenith Bank ti nomba won je 5617984012, 0060949275 ati 1011691254, won si awon account naa nigba ijoba Ambode.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…