Home orisiirisii Dókítà ti pàdánù ẹ̀mí rè.
orisiirisii - Orisirisi - August 20, 2019

Dókítà ti pàdánù ẹ̀mí rè.

 

Dokita kan ni ipinle Eko ti n je Adeyemi David, ti padanu emi re nibi ti o ti n gbiyanju ati ran ara ile ti ina gbe lowo ni opin ose ti o koja.

Iroyin ni, dokita naa wa ni ile nigba ti o gbo igbe eeyan fun iranlowo. O sa bo ita lati ran ara ile re ti ina gbe lowo, amo o se ni laaanu pe ina gbe oun na o si padanu emi re.

Awon molebi re ti n sofo iku re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…