Home Entertainment Bàbá ọmọ Ronke Odusanya ti kí ara rẹ.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 20, 2019

Bàbá ọmọ Ronke Odusanya ti kí ara rẹ.

 

Baba omo Ronke Odusanya, Saheed Aranmolate ti awon eeyan mo si Don Jago ti ki ara re fun omo ti won bi.

Jago ki ara re lori instagram, o si ni “mo dupe lowo olorun fun emi ti o fun mi.. Inu mi dun, mo si setan lati se ise ti o wun mi se. Mo ti sonu lona, nitori naa mo nilo lati se nnkan ti yoo mu inu mi dun.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…