Tunde Owokoniran ti bímọ kejì.
Gbajumo osere onitiata, Tunde Owokoniran, ti bimo keji pelu iyawo re ni orile-ede America.
O so eyi ni ori instagram pelu aworan oun ati iyawo re pelu awon omo re mejeeji.
Olorun n ro ojo omo laaarin awon onitiata ere Yoruba.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…