Home Entertainment Toyin Abraham ti sọ̀rọ̀ nípa ọmọ bíbí rè.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 19, 2019

Toyin Abraham ti sọ̀rọ̀ nípa ọmọ bíbí rè.

 

Gbajumo osere onitiata, Toyin Abraham ti o se mo mi mo e ti o si bimo lenu ojo meta yii, ti soro lori instagram fun igba akoko leyin ti awon isele naa waye.

Toyin ti awon eeyan ti n je oro re lenu lati bii ose kan ni “irinajo ni omo bibi. Isele ojo ayé ni nigba o ba ri pe emi rekii se tìrẹ mo. Koda ninu yara omo bibi, boya o ma ye tabi o ko ni ye, emi re n be lowo oluwa.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…