Home iroyin NYSC : Àgùnbánirọ̀ mẹ́ta ti pàdánù ẹ̀mí wọn nínú Ìjàm̀bá ọkọ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 19, 2019

NYSC : Àgùnbánirọ̀ mẹ́ta ti pàdánù ẹ̀mí wọn nínú Ìjàm̀bá ọkọ̀.

 

Awon agunbaniro meta ti n sin ile baba won ti ipinle Katsina, ti padanu emi won ninu ijamba oko ni Kankara local government area ni ipinle naa ni ana ojo Sunday August 18.

Iroyin ni awon agunbaniro naa n lo fun igbeyawo ni ile ijosin Catholic nigba ti isele naa waye. Okan lara awon to bori ijamba naa ni break failure ni u ojo lo faa. O ni diriba naa n gbiyanju lati lo break amo oko naa ti nomba re je MAN-45-AA ti won ko “CORPERS FOR CHRIST” si lara, ya bara, o si kolu igi.

PRO won, Alex Obemeata lo fi idi eri isele naa mule. O si ni awon ti wo farapa ti n gba itoju lowo ni ile iwosan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…