Home orisiirisii Mike Bamiloye n gbá àwọn osere ní ìmọ̀ràn.
orisiirisii - Orisirisi - August 19, 2019

Mike Bamiloye n gbá àwọn osere ní ìmọ̀ràn.

 

Wolii Mike Bamiloye n gba awon osere ti olorun fun ni eebun ni imoran pe ki won pada si odo oluwa.

O ni awon osere ti olorun fun ni eebun orin, ere tiata, ati awon ohun orin, tio je pe inu soosi ni won ti bere, ti won ya bara si odo esu pe ki won pada si odo oluwa.

O ni bawo ni olorun se ma fun yin eebun, ti e si ma gbe lo si odo esu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…