Home Entertainment Ìdí tí mi ò ṣe gbó – Annie Idibia
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 19, 2019

Ìdí tí mi ò ṣe gbó – Annie Idibia

 

Iyawo gbajumo akorin 2face Idibia, Annie Idibia ti salaye idid ti oun fi n jo omidan ti oun o se gbo.

O ni oun ma n koju mo nnkan ti o kan oun ni, oun o ki n dasi nnkan ti ko kan oun. O ni oun yira oun po awon ti won ni daoun laamu nipa oro siso ati oro okan, o ni oun n nifee denu denu, oun o si ki n so oro oloro leyin, oun si ma n dariji awon ti won ba se oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…