Home orisiirisii Arákùnrin ti ya wèrè.
orisiirisii - Orisirisi - August 19, 2019

Arákùnrin ti ya wèrè.

 

Fidio kan ti n tan kari afefe nipa arakunrin kan ti won ni n se jibiti ori afefe (yahooboy) ti n je Junior ti ya were.

Enikan kan ti isele naa soju re ni arakunrin ti o wa ninu fifio naako lati fimama re sowo, o si ya were, a ko mo bi iro bi ooto ni esun naa. O n so ninu fidio naa pe o ni oun ma lo nnkan omokunrin oun amo won ko gba. O si tun n bere pe kilode to je mama re ti ki n se bab re ni won bere fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…