Home Entertainment Adediwura ti gba òrùka.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 19, 2019

Adediwura ti gba òrùka.

 

Gbajumo osere onitiata, Adediwura Gold ti gba oruka ife leyin odun mejila ti oun ati oko re tele ti pinya, o si ti salaye pe oun ati oko afesona oun ti n ba oro ife awon bo fun odun meta ki o to fun oun ni oruka.

Adediwura tubo so pefun gbogbo igbati oun fi da wa, oun ti ko orisirisi ogbon ti yoo wulo fun oun ninu igbeyawo tuntun yii.

O ni awon ti n fera fun odun meta ki awon to pinnu lati gbe igbese yii, o ni oko afesona oun ti ran oun lowo lati ja awon ogun adaja, pe oun o si lero pe yoo fun oun ni oruka.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…