Home iroyin Update : Wọ́n ti fi arábìnrin tí wón jí gbé sílè.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 17, 2019

Update : Wọ́n ti fi arábìnrin tí wón jí gbé sílè.

 

Won ti fi arabinrin ti n je Mercy Gabriel ti won ji gbe ni Otukpa town ni Ogadigbo local government area ni ipinle Kogi sile.

Agbenuso awon olopaa ipinle Benue, DSP Catherine Anene, lo fi idi eri isele naa mule fun Daily Trust ni omo Friday.

Arabinrin naa ni agunbaniro ti won ji gbe ni ago mesan ale ojo Tuesday ni iwaju soobu re ni Ogadigbo ti awon okunrin merin ti won gbiyanju lati gba a sile padanu emi won ninu ijamba oko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…