Home iroyin Police: Àwọn ọlọ́pàá ti mú àwọn apànìyàn.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 17, 2019

Police: Àwọn ọlọ́pàá ti mú àwọn apànìyàn.

 

Awon olopaa ipinle Enugu ti mu awon ti won fi esun pe won pa awon alufaa ile ijosin Catholic meji kan, pelu awon odaran miran.

Komisona ipinle naa, Ogbeni Sulaiman Balarabe ni won ba orisirisi oun elo ija marundinlogun lowo won nigba ti won ko won ni ojo Friday August 16.

O si ni won lerompe won lowo si iku Rv.Fr. Clemeny Ugwu ti won pa ni March 13 ni Benue ati Abia, o tunbo salaye pe won ti n wa awon merin to ku ti won lero pe won lowo si iku Rev. Fr. Paul Offu pelu oloye ati iyawo re ti won jigbe ni August1 ati 2 ni Agwu Local Government Area.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…