Home orisiirisii Olùkó ti fún akẹ́kọ̀ọ́ lóyún.
orisiirisii - Orisirisi - August 17, 2019

Olùkó ti fún akẹ́kọ̀ọ́ lóyún.

 

Won ti fi esun kan oluko Christian Religious Studies(CRS) ti n je Sola Akinyemi,pe o fun akekoo omo odun marundinlogun loyun.

Won ni oluko naa tan omo naa lo si ile re ati orisirisi ile itura lati ba lopo ni Ondo, pelu ileri pe oun yoo ba gba foonu re ti won gba ni ile iwe. A gbo pe oluko naa lo fi olopaa gbe awon obi omo naa pe won go tyre oko re nigb ti ko gb oyun naa.

Arakunrin kan ti n je Ogbeni Ogunfiditimi ti gba ejo naa, o si ti ko iwe edun si gomina ipinle naa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…