Jamb: wón ti mú akẹ́kọ̀ọ́ tó ṣe jìbìtì èsì ìdánwò rẹ.
Akekoo ti o se United Tertiary Matriculation Examination (UTME) ti fi owo ra re fa wahala leyin ti o se madaru esi idanwo Joint Admissions and Matriculation Board (JAMB) re, won si ti setan lati fa a le olopa lowo.
Won ni Kingsley Unekwe yi esi idanwo re lati 201 si 269 leyin ti o kan si awon ti n se jibiti, nitori awon obi re fe o ka oogun oyinbo ni ile iwe giga. Amo owo pada te e.
Registrar JAMB, Prof Is-haq Oloyede ni omo naa ti jewo ni iwaju mama re ati awon osise miiran ni ojo Friday August 16 pe oun yi esi idanwo oun pada, o si n bebe fun aanu pe oun o mo pe ona jibiti lo ma gba.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…