Home orisiirisii Bí èèyàn bá borí nǹkan ẹ yìn ín – Omoni Oboli
orisiirisii - Orisirisi - August 17, 2019

Bí èèyàn bá borí nǹkan ẹ yìn ín – Omoni Oboli

 

Gbajumo osere onitiata, Omoni Oboli, ti gba awon omo Nigeria ni imoran pe ki won ye bu awon eeyan lori afefe mo.

Imoran naa waye leyin ti awon kan n toka iyawo Adeniyi Johnson tele, Toyin Abraham ti o se mo mi mo e, ti o si bimo okunrin pelu oko re, Kolawole Adeyemi.

Omo so lori Instagram pe “o ye mi ti a bayin eeyan to ba bori nnkan, amo ko da ki a wa ma bu eni keji ti ko bori, nitori inu won ti n baje tele ko si da ki a tun fi kun. Ki i se gbogbo eniyan ni o ni okan tabi ara eebu. Ma je ki eeyan para re nitori oro enu re.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…