Wọ́n ti ti arábìnrin kan bọ́lẹ̀ nínú ọkọ̀.
Arabinrin kan ti awon eeyan o ti i damo ti wa ni ile iwosan General ni Maraba, Karu local government area ni ipinle Nassarawa.
A gbo pe won ti i bole ninu oko ti n rin ni titi Old Karu. Awon ti n koja lo ni titi ni won sare gbe lo si ile iwosan.
Omo naa o ti ni imo to pe nipa nnkan ti o se e, amo o ni omo ipinle Benue ni oun.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…