Toyin Abraham ò tíì ṣe ìgbéyàwó – Manager re.
Manija Toyin Abraham, Samuel Olatunji ti soro nipa igbeyawo Toyin.
Samuel ni aworan Toyin ti o wa kaakiri kii se aworan igbeyawo, o ni aworan mo mi mo e lasan ni, ti o waye ni July 14. O ni mo mi mo e nikan ni won se pe Toyin o tii fe Kolawole gege bi Iyawo ati oko.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…