Home orisiirisii Liposuction: Ẹ ṣọ́rá fún iṣẹ́ abẹ.
orisiirisii - Orisirisi - August 16, 2019

Liposuction: Ẹ ṣọ́rá fún iṣẹ́ abẹ.

 

Arakunrin kan ti kilo fun awon omo Nigeria pe ki won nifee ara won bi ko bo wu ki ara won se ri leyin ti ore re ti o lo se ise abe ni ile iwosan nla kan ni Abuja ni ojo Sunday.

Gege bi @Afu Nwa na Tuwati se so lori Twitter, arabinrin naa je eni ti o ni owo lowo, ti o si n se dada.

Ni ojo Sunday ti o koja, o lo se ise abe ni ile iwosan nla kan ni Abuja lati din ora ara re ku, ise abe naa si yiwo, o si padanu opolopo eje ti o si fa iku re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…