Ìnọ̀ki ti sá kúrò ní ilé rẹ.
Wahala ti be sile ni Yunifasiti ti Ilorin ni ana, leyin ti inoki ti sa kuro ni ile re.
A gbo enikeni o farapa latari isele naa ti o waye ni ana Aug15, amo awon akekoo ti ya orisirisi aworan nibi ti inoka naa ti n sa lo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…