Ìjàm̀bá ọkọ̀ ti pa Àgùnbánirọ̀.
Ijamba oko ti o waye ni ana August 15 ni Lokoja ni ipinle Koji, ti gba emi arabinrin agunbaniro kan yi n je Ebieme Joy.
Agunbaniro naa ti nomba re KG/19B/0052, ni oko Dangote gba ti o ku loju ese.
Ki olorun te emi re si afefe ire
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…