Arákùnrin ti da fóònù padà.
Awon eeyan ti gboriyin fun akarun oni maruwa kan fun iwa rere ti o wu.
Gege bi Gbaja Adeolu se so lori Twitter, o ni oun gbagbe foonu oun (iphone) sinu maruwa, arakunrin ti n w maruwa naa si dapada fun oun laisi iyonu.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…