Toyin Abraham to ṣe ìgbéyàwó.
Gbajumo osere Toyin Abraham se mo mi mo e pelu baba omo re ti o si je onsere onitiata Yoruba, Kolawole Ajeyemi ni ojo Thursday July 4.
Won se mo mi mo e naa ni ile Toyin, awon ti o si wa ni ibe ni Kolawole Ajeyemi, Yeyeluwa Odebunmi, Honorable Segun Odebunmi, mama Toyin ati awon molebi re.
Toyin ti loyun, ko si ni pe bimo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…