Home orisiirisii Kidnapped:Àwọn ọkùnrin mẹ́rin ti pàdánù ẹ̀mí wọn.
orisiirisii - Orisirisi - August 14, 2019

Kidnapped:Àwọn ọkùnrin mẹ́rin ti pàdánù ẹ̀mí wọn.

 

Awon ajinigbe ji arabinrin kan ti n je Gabriel Mercy ni iwJu soobu re ni Ankpa junction, Obu Branch Otukpa, Ogbadibo LGA ni ipinle Benue.

Obinrin naa se pari agunbaniro re, ti o lo se ni ipinle Kogi ni osu ti o koja.

Iroyin ni, leyin ti awon ajinigbe naa ji arabinrin naa gbe ti won si gbe sinu oko, awon arakunrin merin gun okada lati le won mu.

A gbo pe ori okada ni awon arakunrin naa wa ti oko si gba won ti won si ku loju ese. Won si to gbe oku won kuro, ti awon ajinigbe naa si gbe obinrin naa lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…