Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - August 14, 2019

Wọ́n ti dáná sun éégún.

 

Eegun kan ni ipinle Ogun,Danafojura se ere ina fun awon onworan re ni Ojude Oba ni ana August 13.

Awon onworan naa ya orisirisi aworan bi won se dana sun eegun naa ti o si rin jade ninu ina naa ti ko si paa lara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…