Home orisiirisii Rape: Ọlọ́pàá ti gbé arákùnrin tí ó fi ipá bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀
orisiirisii - Orisirisi - August 13, 2019

Rape: Ọlọ́pàá ti gbé arákùnrin tí ó fi ipá bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀

 

Awon olopaa ipinle Ogun ti gbe arakúnrin kan ti n je Emmanuel Ikhine omo odun mejilelaadota dun esun pe o fi ipa ba omo re omo odun mejidinlogun lopo o si fun loyun, ni ojo Satide August 10.

Won gbe arakunrin naa leyin ti Yemisi Ashade kan wa fi ejo arakunrin naa sun pelu omo naa. Omo naa ri fi ejo baba re sun Yemisi, bi o se ma n fi ipa ba oun lopo ti o si ni oun o gbodo so fun enikeni aijebe oun ma fi iya je e.

Agbenuso olopaa ipinke naa, Abimbola Oyeyemi lo fi idi eri isele naa mule, o ni omo naa ro ejeo fun Yemisi leyin ti isele naa su.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…