Home iroyin Hajj 2019: Àwọn ọmọ Nigeria mẹ́sàn-àn ti kú sí Saudi Arabia.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 13, 2019

Hajj 2019: Àwọn ọmọ Nigeria mẹ́sàn-àn ti kú sí Saudi Arabia.

Dr Ibrahim Kana, ti o je Alaga National Medical Team of National Hajj Commission of Nigeria (NAHCON) ti fi idi eri re mule ni August 12, pe awon omo Nigeria mesan-an lo ku nigba ti won n se Hajj 2019 ni Saudi Arabia.

Iroyin naa kan leyin iku Alhaja Folashade Lawal, obinrin omo Nigeria ti omlo fun Hajj lati Oshodi Local Government Area ni ipinoe Eko. Dr Ibrahim Kana tunbo salaye pe awon eeyan meta lati Kano, meji lati Katsina, okan lati Sokoto ati ara oke okun kan lo ku si Hajj ti odun yii.

O fi kun pe ikero opolopo awon eeyan lodoodun ni Hajj ni ara didun nitori itin ana jijin, iko, kata ati aya didun lile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…