Home ÀKỌ̀TUN Dìgbòlugi sójà tó fipá bá aké̩kò̩ó̩ fásítì lò máa fojú ba ilé-e̩jó̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - August 12, 2019

Dìgbòlugi sójà tó fipá bá aké̩kò̩ó̩ fásítì lò máa fojú ba ilé-e̩jó̩

Corporal Sunday Adelola to je soja ti eegun gun si odi, ti o si fi ipa ba akekoobinrin olodun keta ti ile-iwe Adekunle Ajasin to wa ni Akungba lo, ni awon ajo lorisiirisii ti dide pe won ko gbodo ko ejo naa danu bii omi isanwo.
Awon egbe obinrin ipinle naa lo kojko dide ki awon miran to maa fi enu sii.
Awon egbe naa ni awon koko ki awon ologun daadaa bi won se koko yo soja naa kuro ninu ologun orileede yii.
Won ni abaniloruko je ni soja naa. Won ni eyi ti o naa mu ki inu opo omo Naijiria dun ni ti idajo ododo ba tun wa waye lori oran naa.
Alukoro awon olopaa ni ipinle Ondo, Femi Joseph naa fi da awon ara ilu loju pe ko le si ojoro kankan ninu ejo naa. O ni ti igbejo ko ba waye ni ojo ojo’ru ti o n bo yii, a je pe o gbodo waye ni ojo’bo.
Oga olopaa naa ni elese ko ni lo lai je iya.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…