Home orisiirisii Thieves: Àwọn olè ti gbìyànjú àti jí pósí.
orisiirisii - Orisirisi - August 10, 2019

Thieves: Àwọn olè ti gbìyànjú àti jí pósí.

 

Awon ole ti gbiyanju ati ji posi oloogbe onisowo nla Olorogu Mucheal Ibru, eyi si fa wahala ni agbegbe Agbarha-Otor ni Ugheli North Local Government Area ni ipinle Delta.

Vanguard royin pe, awon molebi sakeyesi nnkan ti awon ole naa se ni aaro ojo Friday August 9, eyi si fa ki o ma si irinse ni agbegbe Delta lati ago mejila oru. Awon ole naa o se aseyori leyin ti won da acid si saare naa ti o wa leyin Ibru Clinic.

Omowe Sam Ibodje ti o je Aare gbogbogboo fun agbegbe naa lo fi idi eri isele naa mule, o si ni won ti fi to awon olopaa leti.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…