Home orisiirisii Murder :Arákùnrin ti gba ẹ̀mí èèyàn méjì.
orisiirisii - Orisirisi - August 10, 2019

Murder :Arákùnrin ti gba ẹ̀mí èèyàn méjì.

Awon olopaa ipinle Ogun ti mu arakunrin kan ti won fura si fun apaniyan, pe o yin ibon pa awon eeyan meji ti n gbe ni ilu Iwoye ni Ilaro.

Awon olopaa ni ojo Wednesday leyin osu márùn-ún ti o wu iwa naa ni won wa lo, ti o si ti sa lo.

DSP Abimbola Oyeymi, ni o yin ibon pa Onifade Ajayi kan ni March 27, 2019. Awon won ko mo oun to fa a.

O si tun yin Olatunju Ayinla kan ni ibon, nigba to awon ara adugbo n gbiyanju ati gba ibon owo re.

Abimbola ni arakunrin naa lo farapamo ki o ti di ago mewa ale oje Wednesday, ti awon olopaa gbo nipa ibi ti o wa niIrogun-Ishaga. O ni won ba ibon ibile, ota ibon ati orisirisi oogun lowo re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…