Home iroyin Hajj: Aisha Buhari ti lọ sí Mecca fun Hajj.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 10, 2019

Hajj: Aisha Buhari ti lọ sí Mecca fun Hajj.

 

Aisha Buhari àti awon obinrin akoko orile-ede African kookan ti lo si Mecca lati gbaradi fun Hajj.

Obirin akoko orile-ede Nigeria jo wa pelu awon obinrin akoko orile-ede Guinea Conackry, Niger Republic, Gambia ati Somalia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…