Home orisiirisii Suicide : Arákùnrin ti gba ẹ̀mí ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 9, 2019

Suicide : Arákùnrin ti gba ẹ̀mí ara rẹ̀.

 

Arákùnrin kan ti pa ara re sinu soobu kan ni Nnebisi road Asaba ni ipinle Delta.

Awon eeyan ti won n koja ni won ri oku ni ni aaro oni August 9.

Won ti pe awon olopaa, won si ti gbe oku naa lo si motuari.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…