Home orisiirisii Suicide: Akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin ti pa ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 9, 2019

Suicide: Akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin ti pa ara rẹ̀.

 

Akekoo obinrin omo odun merinla ni ile iwe sekondiri ni Kess Colkege ni Ekredjebor ni agbegbe Ugheli ni Ugheli North Local Government Area ni ipinle Delta ti pa ara nitori ibasepo to wa laaarin oun ati orekunrin o lo deedee.

Gege bi Vanguard se so, oruko ologbee naa ni Favour, won ri oku re lara aja ile won jibi ti o ti fi okun pa ara re, o si ko iwe sile lati ṣàlàyé nnkan to mu pa ara re.

Ore re ti wa si ile won lati ba se irun re lo ri oku re.

Ara adugbo kan no oloogbe naa je omo kan soso ti awon obi re bi, oun nikan lo si wa ni ile nigba ti o hu iwa naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…